Yoruba ponbele. . . . . BBCNEWS Yoruba
Okanlawon Olugbenga wrote:
- Adé òkín, kó jó t’eyekéye.
- Adé òkín, kì í se t’eyekéye.
- Adé òkín, kò le è se déédéé ti eyekéye.
Èyin òjògbón, èwo lo wolè jù nínú òwe yìí?
Adé orí òkín, kó jo t’eyekéye ní mò n gbó.
Òkín l’oba eye, kò sí eyekéye tó rí bí eye arewà yìí. Ìdí nìyíí tí àwon àgbà fi gbà pé adé orí òkín kò je t’eyekéye.
A kú imúra isè òní!